Amina Mama

Amina Mama
Mama ni odun 2019
OrúkọAmina Mama
Ìbí19 Oṣù Kẹ̀sán 1958 (1958-09-19)
Kaduna, Colonial Nigeria
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́feminism, postcolonialism
Ìjẹlógún ganganwomen, militarism, police, neoliberalism, Africa

Amina Mama (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣú kẹsàn-án ọdún1958) jẹ́ oǹkòwé, ajàfúnẹ̀tọ́ àwọn obìnrin àti ọ̀mọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè Gẹẹsi.[2] Àwọn ǹ kan tí ó dojúkọ gangan ni àwọn ǹ kan tí ó jẹ mọ́ ìṣẹ̀lẹ̀ lẹ́yìn ìjọba amúnisìn, ti ológun àti ti abo. Amina ti gbé ní orílẹ̀-èdè Áfíríkà, Yúróoṕù, àti Àríwá Amẹ́ríkà àti wípé ó ti ṣiṣẹ́ láti mú ìbáṣepọ̀ láàrin àwọn onímọ̀ àti olóyè obìnrin kákàak̀iri àgbáyé.

  1. Amina Mama", GWS Africa, 5 August 2008.
  2. "Amina Mama Celebrates Her 62nd Birthday Today". ABTC. 2020-09-19. Retrieved 2020-11-08. 

© MMXXIII Rich X Search. We shall prevail. All rights reserved. Rich X Search